adesinaabegunde_yo_mrk_text.../14/32.txt

1 line
480 B
Plaintext

\v 32 Wón sì wá sí ibi kàn tí à ńpè ní Gẹ́tsímánì, ó sì wí fún àwọn ọmọ èyìn rẹ̀ pé, "Ẹ jókǒ ní ìhín nígbàtí mo bá lọ gbàdúrà. \v 33 Ó sì mú Pétérù àti Jákọ́bù àti Jòhánù pẹ̀lú rẹ̀, ó sì bẹ̀rẹ́ sí ní ìrẹ̀wẹ̀sí ọkàn, ọkàn rẹ̀ sì dàrú gidigidi. \v 34 Ó sì wí fún wọn pé, "Ọkàn mi ńkãnu gidigidi, títí dé ojú ikú. Ẹ dúró níhǐn kí ẹ sì mã ṣọ́nà.