adesinaabegunde_yo_mrk_text.../14/17.txt

1 line
375 B
Plaintext

\v 17 Nígbàtí alẹ́ lẹ́, ó wá pẹ̀lú àwọn méjìlá. \v 18 Bí wọ́n sì ti jókǒ tí wọ́n ń jẹun, Jésù wípé, "Lõtọ ni mo wí fún n yín, ọ̀kan nínú yín tí ó ń bá mi jẹun yíò fi mí hàn. \v 19 Wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí ní kãnú gidigidi, wọ́n sì ń bi ra wọn léérè lẽre lọ́kọ̃kan wípé, "Èmi ni bí?