adesinaabegunde_yo_mrk_text.../14/12.txt

1 line
615 B
Plaintext

\v 12 Ní ọjọ́ kínǐ àjọ àìwúkárà, nígbàtí wọ́n pa ẹran ìrékọjà, àwọn ọmọ ẹ̀yìn wí fún n pé, "Níbo ni ìwọ fẹ́ kí á lọ pèsè sílẹ̀, kí ìwọ́ kí ó le jẹ ìrékọjá. \v 13 Ó sì rán méjì nínú àwọn ọmọ ẹ̀yin ó sì wí fún wọn pé, "E lọ sí iń ìlú, okùnrin tí ń ru 777 omi yíò pàde yín. Ẹ tẹ̀lẹ́ e. \v 14 NÍbití ó bá ti wọlé, ẹ tẹ̀lé e kí ẹ sì wí fún onílé wípé, 'Olùkọ́ni wípé, "NÍbo ni yàrá ìgbàlejò tí èmi yíò ti jẹ ìrékọjá pẹ̀lú àwọn ọmọ èyìn mi?"