adesinaabegunde_yo_mrk_text.../14/01.txt

1 line
328 B
Plaintext

\c 14 \v 1 Ó ku ọjọ́ méjì sí àjọ ìrékọjá àti àjọ àíwúkárà. Àwọn olórí àlúfà àti akọ̀wé ń ro bí wọn yí ò ti rora mú Jésù láì fura kí wọn sí pá. \v 2 Nítorí wón ń sọ wípé, "Kìí se nígbà ọdún, kí rúkèrúdò má baà sẹlẹ̀ láàrín àwọn ènìyàn.