1 line
415 B
Plaintext
1 line
415 B
Plaintext
\v 26 Ṣùgbọ́n nípa àjíǹde tó ti kú, ẹ̀yin kò ì tí ka nínú ìwé Mósè, àkọsílẹ̀ pápá tí ń jó, bí Ọlọ́run se bá Mósè sọ̀rọ̀ tó wípé, ‘Èmi ni Ọlọ́run Ábráhámù, Ọlọ́run Ísáákì àti Ọlọ́run Jákọ́bù’? \v 27 Òun kì í ṣe Ọlọ́run àwọn òkú, bí kò ṣe Ọlọ́run àwọn alààyè. Ẹ̀yin ṣe àṣìṣe gidigidi.” |