\v 35 35 Nígbàtí ọjọ́ ti lọ àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ wá sọ́dọ̀ rẹ̀,wọ́n sì wípé "Inú ijù ni èyí ilẹ̀ sì ti sú. \v 36 Rán wọn lọ, kí wọn kí ó lọ sí ìlú tí ó súnmọ́n àti ìgbèríko, kí wọn kí ó lọ ra ohun tí wọn yóò jẹ fún ara wọn.