\v 35 Bí ó ti ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, àwọn kan wá láti ọ̀dọ̀ olórí sínágọ́gú, wípé "Ọmọ rẹ obìnrin ti kú, kí ló dé tí ó ńyọ Olùkóni lẹ́nu?"