adesinaabegunde_yo_mrk_text.../05/07.txt

1 line
274 B
Plaintext

\v 7 Ó pariwo jade lóhùn òkè, "Ki ni mo ni se pẹ̀lú rẹ, Jésù ọmọ Ọlọ́run ọ̀gá ògo? Mo bẹ Ọ lórúkọ̀ Ọlọrun nìkan, máse fòró mi." \v 8 Nítorí ti o ti ń sọ fún "jáde kúrò lára ọkúnrin náà, ìwọ ẹ̀mi àìmọ́."