|
Bakana ni awon olori alufa se eleya re laarin ara won, pelu awon akowe, won si wipe, "O gba awon miran sugbon ko le gba ara re. Jeki Kristi naa, oba Isreli naa, sokale nissisiyi, ki awa le rii, ki a si gbagbo," awon ti a kan mo agbelebu pelu re naa si kegan re. |