adesinaabegunde_yo_mrk_text.../06/07.txt

1 line
314 B
Plaintext

\v 7 \v 8 \v 9 O si pe awon mejila, O ran won jade ni meji meji, O si fun won ni agbara lori emi aimo. O si wi fun won pe, won ko gbodo mu ohun kohun dani fun irinajo naa, bikose opa itile won, won kogbodo mu akara tabi gbe apo tabi owo sinu igbadi won. Sugbon, ki won ki o wo bata, ki won ma si mu aso ibori dani.