|
\v 4 \v 5 \v 6 Jesu si wi fun won pe, Woli kin lola larin ilu re, ati lodo awon eniyan re, ati ninu ile re. Ko si le sise iyanu larin won, O kan gbe owo le awon alaisan die, O si wo won san. Enu si yaa nitori aigbagbo won, O si jade lo si awon abule lati ko won ni oro Olorun. |