1 line
297 B
Plaintext
1 line
297 B
Plaintext
\v 21 Anfani lati pa a wa nigbati Oba Herodu se ojo ibi, osi se ase fun awon emewa re, awon alase ati awon adari ni ile Galili. \v 22 Omobirin Herodia si wa fi ijo da Herodu ati awon alejo re laraya. Oba Herodu si wipe fun omobirin na pe: "bere ohun kohun ti o ba fe ni owo mi, emi o si fi fun o." |