adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/09.txt

1 line
365 B
Plaintext

\v 9 Pílátù dáwọn lóhùn wípé, "Ǹjẹ́ ẹ̀yin fẹ́ kí èmi fi Ọba àwọn Júù lé e yín lọ́wọ́ bi?" \v 10 Nítorí ó mọ̀ pé àwọn olórí àlùfáà fi Jésù lé òun lọ́wọ́ nítorí owú ni \v 11 Ṣùgbọ́n àwọn olórí àlùfáà ru àwọn èrò sókè láti pariwo pé Baraba ni kí ó fi sílẹ̀ (ẹ̀wẹ̀).