adesinaabegunde_yo_mrk_text.../05/41.txt

1 line
397 B
Plaintext

\v 41 O si mu ọwọ ọmọ naa o si wi fun wipe, "Talitha Koum!" eyi ti o tumọ si wipe, "ọmọbinrin, mo wi fun ọ, dide." \v 42 Loju kana, ọmọ naa dide, o si nrin (O je ọmọ ọdun mejila nigbana). Lẹsẹkanna ẹnu ya wọn ibẹru bojo si mu ọkan wọn. \v 43 O si pasẹ fun wọn wipe, ẹnikẹni ko gbọdọ mo ni pa rẹ. O si wi fun wọn wipe, ki wọn fun louje je.