adesinaabegunde_yo_mrk_text.../05/30.txt

1 line
358 B
Plaintext

\v 30 Jésù sì ní ìmọ̀lára wípé agbára ti jáde kúrà lára òhun. Ó wò yíká láàrín èrò wípé, "tani ó fọwọ́ kan asọ mi?". \v 31 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ wí fún pé, "O ri bi àwọn ènìyàn yìí tí yípo rẹ, ó sì ni, "tani ó fọwọ́ kàn mí?" \v 32 Jésù wò yíká láti rí ẹni tó ṣe eléyìí.