adesinaabegunde_yo_mrk_text.../05/11.txt

1 line
439 B
Plaintext

\v 11 Ó sì se, agbo awọn ẹlẹ́dẹ̀ sì jẹun lórí òkè, \v 12 Wọ́n sì bẹ́ẹ̀, wípé, "Rán wa lọ sí inú agbo ẹlẹ́dẹ̀; kí a sì wọ inú wọn lọ." \v 13 Ó sì gbà wọ́n láyè; àwọn ẹ̀mí àìmọ́ náà sì jáde, wọ́n sì wọnù àwọn agbo ẹlẹ́dẹ̀ lọ, wọ́n sì sáré sọ̀kalẹ̀ lọ sínú òkun, bí ẹgbẹ̀rún méjì ẹlẹ́dẹ̀ si parun sínú òkun.