|
\v 3 Okúnrin náà ma gbé nínú isà-òkú . Kò sì si ẹni tí o le dá mu, koda pelu ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀. \v 4 Wón ti ma ń dé è lọ́pọ̀lọpọ ìgbà pẹ̀lú ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀ ọwọ́ atì tẹsẹ̀. Ọkùnrin yíì ma ń gé ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀ tọwọ̀ atì tẹsẹ̀ sí wẹ́wẹ́. Kòsi sí ẹni tí agbára rẹ̀ káa. |