2 lines
451 B
Plaintext
2 lines
451 B
Plaintext
\v 63 Olórí àlùfáà sì fa asọ rẹ̀ ya ó sì wípe, "Sé a sì nílò ẹlẹ́rǐ bí? \v 64 Ẹ̀yín ti gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹ̀gàn náà. Kíni ìpinu yín? Gbogbo wọn sì kẹ́gàn rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi ẹni tí ó yẹ fún ikú.
|
|
\v 65 Àwọn míràn bẹ̀rẹ̀ sí ní tutọ́ síi lára wọ́n sì bo ojú rẹ̀ wọ́n sì lû wọ́n wí fun pé, "sọtẹ́lẹ̀!" Àwọn ọmọ ogun sì mú wọ́n sì lùú. |