adesinaabegunde_yo_mrk_text.../13/30.txt

1 line
404 B
Plaintext

\v 30 Nítòótó, mo sọ fún un yín, ìran yí kò ní kọjá lọ títí gbogbo ǹkan wọ̀nyi yóò fi wá sí ìmúṣẹ. \v 31 Ọ̀run àti ayé yíò kọjá lọ, ṣùgbọ́n àwọn ọ̀rọ̀ mi kì yóò kọjá. \v 32 Ṣùgbọ́n nípa ọjọ́ náà tàbí wákàtí náà, ẹ́nìkan kò mọ̀, kódà àwọn ángélì, tàbí Ọmọ, bíkòṣe Baba nìkan ní ò mọ̀.