adesinaabegunde_yo_mrk_text.../13/24.txt

1 line
583 B
Plaintext

\v 24 Ṣùgbọ́n lẹ́yìn ìpọ́njú àwọn ọjọ́ náà, oòrùn yio ṣóòkùn, òṣùpá kì yíò tan ìmọ́lẹ̀ rẹ̀, \v 25 àwọn ìrawọ̀ yio jábọ́ lati òkè, àti àwọn agbára ti o wà lọ́run yíó mì. \v 26 Nígbànáà ni nwọ́n o rí Ọmọ Ènìyàn tí ó ǹsọ̀kalẹ̀ láti inú àwọọ́sánmọ̀n pèlú agbára àti ògo. \v 27 Nígbànáà ni yíò ràń àwọn ángẹ́lì rẹ̀, yio si ko àwọn àyànfẹ́ rẹ lati inú orígun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin, láti òpin ayé títí dé òpin àwọọ́sánmọ̀n.