adesinaabegunde_yo_mrk_text.../13/21.txt

1 line
447 B
Plaintext

\v 21 Nígbànáà, bí ẹnikẹ́ni bá sọ fùn un yín pé, 'wò ó, èyí ni Krísìtì náà!' Wò ó, níbìyí ló wà! má ṣe gbàágbọ́. \v 22 Nítorí èké Krístì àti èké wòlíì yóò farahàn, nwọ̀n o si fi àmìn àti iṣẹ́-ìyanu han, láti le tanni, tí ó bá ṣeéṣe, àwọn àyànfẹ́ náà pèlú. \v 23 Ẹ wà ní ìṣọ́ra! Èmí ti ńsọ ǹkan wọ̀nyí fún yín ṣáájú àkokò náà.