adesinaabegunde_yo_mrk_text.../13/01.txt

1 line
385 B
Plaintext

\c 13 \v 1 Bí Jésù ti ń lọ kúrò ni tẹ́ḿpílì, ọ̀kan nínú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ wí fun pé. "Olùkọ́ni, wo òkúta iyebíye àti àwọn ilé iyebíye!" \v 2 Ó sì sọ fún n wípé, "Ǹjẹ́ ìwọ́ rí àwọn ilé ńlá yìí? Kò sí ọ̀kan nínú àwọn òkúta wọ̀nyí tí yíò dúró lórí ara wọn tí a kò ní dàwó lulẹ̀.