adesinaabegunde_yo_mrk_text.../12/41.txt

1 line
368 B
Plaintext

\v 41 Jésù sî jókòó ní òdìkejì kọjú sí àpótí ìṣúra ní tẹ́ḿpílì; ó ń wo ìjọ ènìyàn ti ń sọ owó sínú àpótí ìṣúra. Opọ̀ àwọn ọlọ́rọ̀ sì sọ púpọ̀ sí i. \v 42 Ṣùgbọ́n obìnrin opó kan wà, ó sì fi ààbọ̀ owó idẹ méjì síbẹ̀, tí ì ṣe ìdá méjì owó-babà kan sínú rẹ̀.