adesinaabegunde_yo_mrk_text.../12/24.txt

1 line
337 B
Plaintext

\v 24 Jesu wí fún wọn pé, “Kì í há ṣe nítorí èyí ni ẹ ṣe ṣìnà, nítorí ẹ̀yin kò mọ ìwé Mímọ́ tàbí agbára Ọlọ́run? \v 25 Nítorí pé, nígbà tí wọ́n bá jí dìde nínú òkú, a kò ní ṣe ìgbéyàwó fún wọn, ṣùgbọ́n wọn dàbí àwọn angẹli tí ń bẹ ní ọ̀run.