1 line
313 B
Plaintext
1 line
313 B
Plaintext
\v 17 O si ko won wipe, Se bi ati ko wipe "a o ma pe ile mi ni ile adura fun gbogbo orile ede? Sugbon eti so di ogba awon ole. \v 18 Awon olori alufa ati awon akowe gbo ohun ti o so, won si n wa ona lati pa. Nitori won beru re tori opo ero ti enu ya nitori eko re. \v 19 Nigba ti o di irole, won fi ilu naa sile. |