adesinaabegunde_yo_mrk_text.../11/07.txt

1 line
393 B
Plaintext

\v 7 omo eyin meji naa mu ketekete naa wa sodo Jesu won si te aso won sori re ki Jesu le gun ketekete naa. \v 8 Opo eniyan si te aso won sile ni oju ona, awon miran si te imo ti won ti ge lati inu oko. \v 9 Awon ti o nlo niwaju re ati awon ti o n bo lehin re n kigbe, "Hosana! Ibukun ni eni ti o wa ni oruko Oluwa. \v 10 Ibukun ni fun ijoba baba wa Dafidi ti n bo wa! Hosana ni ibi giga julo."