1 line
562 B
Plaintext
1 line
562 B
Plaintext
\v 46 Wọ́n wá sí Jẹ́ríkò. Bí ó se fi Jẹ́ríkò sílẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ èrò, ọmọ Tíméaù, Bátólóméù afọ́jú tí ó ntọrọ, jókòó ní ẹ̀bá ọ̀nà. \v 47 Nígbàtí ó gbọ́ pé Jésù ti Násárẹ́tì ni, ó bẹ̀rẹ̀ síi kígbe wípé, "Jésù ọmọ Dáfídì sàánú fún mi". \v 48 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ló bá afọ́jú náà wí, pé kí ó pa ẹnu rẹ̀ mọ́. Ṣùgbọ́n ó kígbe lóhùn rara síi "ọmọ Dáfídì sàánú fún mi!" |