adesinaabegunde_yo_mrk_text.../10/10.txt

1 line
362 B
Plaintext

\v 10 Nígbàtí wọ́n wà nínú ilé, àwọn ọmọ ẹyìn bèrè lẹ́ẹ̀kan si nípa èyí. \v 11 Ó wí fún wọn pé, "ẹnikẹ́ni tí ó bá kọ ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀ tí ó si gbé obìnrin míràn ní ìyàwó ó se panságà síi. \v 12 Bí obìnrin bá kọ ọkọ rẹ sílẹ̀ tí ó si fẹ́ ọkùnrin míràn, ó se panságà."