adesinaabegunde_yo_mrk_text.../09/14.txt

1 line
436 B
Plaintext

\v 14 Nígbàtí wọ́n dé ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ-ẹ̀yìn yókù, wọ́n sì rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ èrò yí wọn ká bẹ́ẹ̀ni àwọn akọ̀wé sì ń bá wọn wíjọ́. \v 15 Bí wọ́n ti rí Jésù, ẹnu ya ọ̀pọ̀lọpọ̀ èrò náà bẹ́ẹ̀ni wọ́n sáré pàdé rẹ̀ wọ́n sì kíi. \v 16 Ó bi àwọn ọmọ ẹ̀yìn Rẹ̀ wípé, "Kíni ẹ̀yin bá wọn se àríyànjiyàn síi?"