adesinaabegunde_yo_mrk_text.../09/11.txt

1 line
583 B
Plaintext

\v 11 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn bi Jésù léèrè pé, "Èéṣe tí àwọn akọ̀wé fi ṣọ wípé Èlíjà ni ó gbọ́dọ̀ kọ́kọ́ wá."? \v 12 Jésù wí fún wọn pé, "Èlíjà ti kọ́kọ́ wá ná láti mún ohungbogbo padàbòsípò.Èéṣe tí a wá fi kọ̀wé rẹ̀ pé Ọmọ ènìyàn gbọ́dọ́ jìyà ohun púpọ̀ kí á sì se Ṣé bíi ẹni tí kòní láárii? \v 13 Ṣùgbọ́n èmi wí fún n yín pé Èlíjá ti wá ná, wọ́n sì seé ohun gbogbo tí ó wù wọ́n síi, gẹ́gẹ́ bí ìwé mímọ́ ti wí nípa rẹ̀."