adesinaabegunde_yo_mrk_text.../09/01.txt

1 line
581 B
Plaintext

\c 9 \v 1 Jésù sì wi fún wọn pé, "Lóòtọ́ọ́ ni mo wí fún yín, ọ̀pọ̀lọpọ̀ nínú yín tí ó dúró níhìńyí ní kì yíò rí ikú kí wọ́n tó rí ìjọba ọlọ́run tí yíò dè pẹ̀lú agbára." \v 2 Lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́fà, Jésù mú Pétérù àti Jákọ́bù àtiJòhánù pẹ̀lú Rẹ̀ lọ sórí òkè gíga, wọ́n dáwà níbẹ̀. A sì paá láradà níwájú wọn. \v 3 Aṣọ Rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ síí tàn bí i mọ̀nàmọ́ná, ó funfun bí ọṣẹ ìfọṣọ ayé kan ìbá fi fọ̀ ọ́ lọ.