adesinaabegunde_yo_mrk_text.../07/36.txt

1 line
407 B
Plaintext

\v 36 Jésù kìlọ̀ fún wọn pé kí wọ́n máse sọ fún ẹni kankan. Sùgbọ́n bí Ó ti ń kìlọ̀ fún wọn tó bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n sì ń polongo Rẹ̀ síi. \v 37 Ẹnu ya àwọn ènìyàn kọjá gidigidi, wọ́n sì ń wípé, "Ó ti se gbogbo ǹkan dáradára. Ó mú kí adití gbọ́ràn, Ó sì mú kí ẹnití kò le sọ̀rọ̀ di ẹnití ó ńsọ̀rọ̀."