adesinaabegunde_yo_mrk_text.../07/31.txt

1 line
341 B
Plaintext

\v 31 Jésù tún kúrò ní agbègbè Tírè, Ó sì gba inú Sídónì lọ sí òkun Gálílì, ní ìgòkè lọ sí agbègbè Dẹ́kápólísì. \v 32 Àwọn ènìyàn gbé ẹnìkan tí kò gbọ́ ọ̀rọ̀, tí ó sì nira fún láti sọ̀rọ̀ wá sí ọ̀dọ̀ Jésù, wọ́n sì bẹ̀bẹ̀ wípé kí Jésù wòó sàn.