adesinaabegunde_yo_mrk_text.../07/27.txt

1 line
449 B
Plaintext

\v 27 Jésù wí fún un pé, "Jẹ́ kí àwọn ọmọ ilé Ísrẹ́lì kọ́kọ́ jẹhun ná, nítorípé kò dára kí á wá lọ gbé ohunjẹ àwọn ọmọ kí á lọ gbée fún àwọn kéfèrí." \v 28 Ṣùgbọ́n Obìnrin yìí dáhùn, ó wí fún Jésù pé, "Bẹ́ẹ̀ni, Olúwa, àwọn kèfèrí pàápàá le jẹ ẹ̀rúnrún ohúnjẹ àwọn ọmọ Ísrẹ́lì tí ó bá bọ́ sí ilẹ̀ láti oríi tábìlì."