adesinaabegunde_yo_mrk_text.../07/20.txt

1 line
536 B
Plaintext

\v 20 Ó wípé, ọ̀rọ̀ àti ìse tí ó jáde wá láti inú ènìyàn sí òde ni ó ń sọ ènìyàn di aláaìmọ́. \v 21 Nítorípé nínú ènìyàn, láti inú ọkàn wá ni àwọn èrò burúkú ti ń jáde wá, ìsekúse, olè jíjà, ìpànìyàn, \v 22 panságà, ojúkòkúrò, ìkà, ẹlẹ̀tàn, ọlọgbọ́n lójú ara rẹ̀, ìlàra, abaníjẹ́, agbéraga, aláìnírònú. \v 23 Láti inú ọkàn ni gbogbo ibi wọ̀nyí ti máa ń jáde wá, àwọn ló sì ń so ènìyàn di aláìmọ́."