adesinaabegunde_yo_mrk_text.../07/11.txt

1 line
508 B
Plaintext

\v 11 Ṣùgbọ́n ẹ̀yin wípé, 'Bí ènìyàn kan bá sọ fún bàbá tàbí ìya rẹ̀ pé, "Ìrànlọ́wọ́ yòówù tí ó yẹ tí o kò bá rí gbà lọ́wọ́ọ̀ mi Kóbánì ni,"' (èyí ni, "Mo ti fi fún Ọlọ́run")- \v 12 Ẹ kò wá jẹ́ kí ọmọ le se ǹkankan fún bàbá tàbí ìya rẹ̀ mọ́. \v 13 Ẹ ń pa òfin Ọlọ́run rẹ́ nípa àsà àtọwọ́dọ́wọ́ tí ẹ gbé kalẹ̀. àti ọ̀pọ̀ àwọn nǹkan bíi irú ìwọ̀nyí ni ẹ se.