adesinaabegunde_yo_mrk_text.../06/56.txt

1 line
268 B
Plaintext

\v 56 Nígbákúgbà tí ó bá wọ ìletò, ìlù tàbí orílè èdè, wọ̀n ń gbé àwọn aláìsán wá láti inú ọjà. Wọ́n bẹ̀ẹ́ kí wọn kí o le fọwọ́kan ìṣẹ́tì aṣọ rẹ̀, iye àwọn tí ó fọwọ́kǎn ni a mú láradá.