adesinaabegunde_yo_mrk_text.../06/53.txt

1 line
398 B
Plaintext

\v 53 Nígbàtí wọ́n sì ti rékọjá, wọ́n wá sí ilẹ̀ Généṣárẹ́tì, wọ́n sì tu ọkọ̀ ojú omi. \v 54 Nígbàtí wn sì jáde kúrò nínú ọkọ̀ ojù omi náà, àwọn ènìyàn dá mọ̀n lọ́gán, \v 55 wọ́n sí sáré kiri gbogbo agbègbè náà láti lọ gbé àwọn aláìsàn wá lórí akètè wọn sí ibikíbi tí wọ́n gbọ̀ pé ó wà.