adesinaabegunde_yo_mrk_text.../06/45.txt

1 line
421 B
Plaintext

\v 45 Lójijì ni ó ní kí àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ wọ ọkọ̀ ojú omi kí wọ́n sì síwájú rẹ̀ lọ sí apákejì lọ sí Bẹtisáídà, nígbà tí ó rán mí àwọn ìjọ ènìyàn lọ. \v 46 Nígbàtí wọ́n sì ti lọ, ó lọ sí orí òkè lọ gbàdúrà. \v 47 Ní gbà tí ó di àṣálẹ́, ọkọ̀ ojú omi náà sì wà nì àrin òkun, òun nìkán sì wà nílẹ̀