adesinaabegunde_yo_mrk_text.../06/42.txt

1 line
194 B
Plaintext

\v 42 Gbogbo wọn jẹun títí tí wọ́n fi yó. \v 43 Wón sì kó mí àjẹkù agbọ̀n méjìlà . \v 44 Iye àwọn tí ó jẹ ìsù àkàrà náà ní se ẹgbẹ̀rún mǎrún.