adesinaabegunde_yo_mrk_text.../06/33.txt

1 line
412 B
Plaintext

\v 33 33 Sùgbọ́n nígbà tí wọ́n rí i tí wọ́n lọ àwọn púpọ̀ dáwọn mòn,wọ́n sì ṣáré pèlu ẹṣẹ̀ láti gbogbo ìlú wọ́n sì síwájú wọn dẹ́ ibè. \v 34 Nígbàtí wọ́n dé èbúté, ó rí èrò púpọ̀ ànú rẹ̀ sì ṣe wọ́n, nítorí tí wọ́n dàbi àgùtàn tí kòní olùṣọ́. Bẹ́ẹ̀ ni ó bẹ̀ẹ̀rẹ̀ síní kọ́ wọn.