adesinaabegunde_yo_mrk_text.../06/30.txt

1 line
428 B
Plaintext

\v 31 \v 30 30 Àwọn àpóstélì padà tọ Jésù wá wọ́n sì sọ fún gbogbo inkàn tí wọ́n ti ṣe àti tí wọ́n ti kọ́. Ó sì ṣọ fún wọn pé" Ẹ wá fún ra yín sínú ijú kí ẹ sì sinmi díẹ̀ nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni wọ́n lọ tí wọ́n bọ̀ láì ní ààyè láti jẹun. \v 32 Bẹ́ẹ̀ni wọ́n lọ kúrò nínú ọkọ̀ ojú omi sínú aginjù láti sinmi.