adesinaabegunde_yo_mrk_text.../06/21.txt

1 line
443 B
Plaintext

\v 21 Àǹfàní láti pa á wá nígbàtí Ọba Hẹ́rọ́dù se ọjọ́ ìbí, ósì se àsè fún àwọn ẹmẹ̀wà rè, àwọn aláṣẹ àti awọn adarí ní ilẹ́ Gálílì. \v 22 Ọmọbìrin Hẹrọdíà sì wá fi ijó dá Hẹ́rọ́dù àti àwọn àlejò rẹ̀ lárayá. ẹ́ba Hẹ́rọ́dù sì wípé fún omobìrin náá pé: "bèrè ohun kóhun tí o bá fẹ́ ní ọwọ́ mi, emí ó sì fi fún ọ."