adesinaabegunde_yo_mrk_text.../06/18.txt

1 line
442 B
Plaintext

\v 18 Nítorí Jòhánù bá Hẹ́rọ́dù wí, "pé kò tọ̀nà láti yan aya arákùnrin rẹ̀ lálè." \v 19 Hẹrọdíà sì bínú sí Jòhánù, ó sì ń wá ọ̀nà láti pa á, èyí sì nira fún \v 20 nítorí Hẹ́rọ̀dù bẹ̀ru Jòhánù. Àti wípé ó mọ̀n pé olódodo àti ènìyan mímó ni, ó sì pa á mọ́n. Gbígbọ́ ọ̀rọ rẹ̀ má ń bíi nínú, sùgbọ́n ó má n fi ayọ̀ gbọ́ ọ.