adesinaabegunde_yo_mrk_text.../06/16.txt

1 line
285 B
Plaintext
Raw Permalink Blame History

This file contains ambiguous Unicode characters

This file contains Unicode characters that might be confused with other characters. If you think that this is intentional, you can safely ignore this warning. Use the Escape button to reveal them.

\v 16 Sùgbọ́n nígbàt´ Hẹ́rọ́dù gbọ́ èyií, ó wípé "Jòhánù tí mo gé orí rẹ̀, ti jí dìde." \v 17 Nítorí Hẹ́rọ́dù ránṣẹ́ láti mú Jòhánù, ó sì jú sẹ́wọ̀n nítorí Hẹrodíà, aya arákùnrin rẹ̀ Fílípì tí ó yàn lálè.