adesinaabegunde_yo_mrk_text.../06/12.txt

1 line
230 B
Plaintext

\v 12 Wọ́n sì jáde lọ láti kéde pé kí àwọn ènìyàn yípadà kúrò nínú ẹ̀sẹ̀ wọn. \v 13 Wọ́n lé àwọn ẹ̀mí èsù jáde, wọ́n fi òróró kun àwọn aláìsàn wọ́n sì gba ìmúláradá.