adesinaabegunde_yo_mrk_text.../06/07.txt

1 line
442 B
Plaintext

\v 7 Ó sì pe àwọn méjìlá, Ó rán wọn jáde ní méjì méjì, Ó sì fún wọn ní agbára lórí àwọn ẹ̀mí àìmọ́. \v 8 Ó wí fun wọn pé; ẹ kò gbọdọ̀ mú ohun kóhun dání fún ìrìnàjò yí, bíkòse ọ̀pá ìtìlẹ̀ yín, ẹ kògbọdọ̀ mú àkàrà tàbí gbé àpó tàbí mú owó sínú ìgbàdí. \v 9 Sùgbọ́n, kí wọn kí o wọ bàta, kí wọ́n má sì mú asọ míràn dání.