adesinaabegunde_yo_mrk_text.../06/01.txt

1 line
692 B
Plaintext

\c 6 \v 1 Ó sì jáde lọ sí ìlú abínibí rẹ̀, àwọn ọmọ ẹ̀yin rẹ̀ sì tẹ̀ le. \v 2 Nígbàtí ódi ọjọ́ Ìsinmi, Ó nkọ́ wọn nínú sínágógù. Òpò ènìyàn sì gbọ́ ẹ̀kọ́ náà, ẹnú sì yà wọ́n. Wọ́n sì bèèrè wípé, "níbo ni o ti rí gbogbo ẹ̀kọ́ tí ò ń kọ́ ni yí?" "Irú ọgbọ́n wo ni afi fún yìí?" "Irú àwọn isẹ́ ìyanu wo ni ó ń\ fi ọwó rẹ̀ se wọ̀nyí?" \v 3 "Sẹ́ kìí se gbénàgbénà náà nì yí, ọmọ bíbí Màríà, àti arákùnrin Jémìsì, àti Jósè, àti Júdà, àti Símónì? Sebí àwọn arábìrin rẹ̀ ń gbé pẹ̀lu wa?" Inú Jésù sì bí wọn.