adesinaabegunde_yo_mrk_text.../05/36.txt

1 line
417 B
Plaintext

\v 36 Nígbàtí ohun tí wọ́n sọ dé etí ìgbo Jésù, Ó sọ fún olórí sínágọ́gú pé "Má bẹ̀rú, ìwọ sá gbàgbó". \v 37 Kò si gba ẹnikẹ́ni laye láti tẹ̀le, àyàfi Pétérù, Jákọ́bù ati Jòhánù arákùnrin Jákọ́bù. \v 38 Wọ́n sì wá sí ilé olórí sínágọ́gú, Ó sì ri àwọn ènìyàn tí wọ́n pariwo; wọ́n sọkún, wọ́n sì ké rora sókè.