adesinaabegunde_yo_mrk_text.../05/33.txt

1 line
317 B
Plaintext

\v 33 Obìnrin náà, nítorí ó mọ ohun tí ó sẹlẹ̀, ó si bẹ̀rù pẹ̀lú ìwárìrì. Ó wa, ó sì kùnlẹ́ níwáju Rẹ̀, ò sí sọ òtítọ́ fún ún. \v 34 Ò sí wí fun pè, "Obìnrin, ìgbàgbọ́ rẹ mú ọ láradá. Ma lọ lalafia ki o si gba ìwòsàn kúrò nínú àrùn rẹ.